ɔ̀ɾɔ̀-oɾúkɔ
(Psittacula krameri)-
ararú òfèé abirù gígùn tìí wọ́n máa ń gbé sùnmọ̀mìí lọ sí oko ní ọ̀wọ̀ọ́ l’áti jẹ ọkà èyìí-ké-èyìí kò báà jẹ̀ẹ́ ọkà àgbàdo tàbìí ọkà’a bàbà; ẹyẹ yìí ní irun ọbẹ̀dọ̀, àgòógó kpukpa; akọ ẹyẹ nọ́ọ̀ ní irun dúdú tí ó ká ní ọrùn
Àwọn téédé máa ń ṣe ìbàálòkpọ̀ ní òṣù Ṣẹẹrẹ sí Ẹrẹ́nọ̀ àti ní Òkùdùú sí Ògùún, ní ìbẹ̀rẹ̀ àti ààrin àkòókò òjò.