Ìtumọ̀ àǹdọ́lá ní èdè Yorùbá:

àǹdọ́lá

Ohũ̀ /do do mi mi/

ɔ̀ɾɔ̀-oɾúkɔ

  • oun tàbìí ẹni tí a kò ṣe àkiyèsìí fún tàbìí tí a kò bu iyì fùún bóyá nítorí a rò pèé kò nìí láárí tàbìí kò ṣe ọ̀wọ̀ọ́n

    Ọmọ tí wọ́n fi ṣe àǹdọ́lá ní ọjọ́ ànọ̀ọ́ ni ó ti wá di òṣèlùú ní òde ònìí.
    • Má ṣe fi ọ̀rọ̀n yìí ṣe àǹdọ́lá, ó mà tòó ẹjọ́!
    àìnìí-láárí
    iyì

Orí-Ìsũ

a kò nìí dá ní ọlá == a kò nìí dá l’ọ́lá {a + kò + ní + dá + ní + ọlá }