ɔ̀ɾɔ̀-oɾúkɔ
-
oun tàbìí ẹni tí a kò ṣe àkiyèsìí fún tàbìí tí a kò bu iyì fùún bóyá nítorí a rò pèé kò nìí láárí tàbìí kò ṣe ọ̀wọ̀ọ́n
Ọmọ tí wọ́n fi ṣe àǹdọ́lá ní ọjọ́ ànọ̀ọ́ ni ó ti wá di òṣèlùú ní òde ònìí.- Má ṣe fi ọ̀rọ̀n yìí ṣe àǹdọ́lá, ó mà tòó ẹjọ́!
àìnìí-lááríiyì
Orí-Ìsũ
a kò nìí dá ní ọlá == a kò nìí dá l’ọ́lá {a + kò + ní + dá + ní + ọlá }