Meaning of in Yoruba
What does mean in Yoruba
Itumo ni Yoruba
kí ẹ̀dàá yọ ara’a rẹ̀ kùúrò nìí ibi tí ó ní ewu, kpàákpàá tí yíyọ nọ́ọ̀ ṣòro, tí ó fẹ́rẹ̀ máà yege
jà + bọ́
Àwọn ọ̀rọ̀ tìí ayé ń tẹ̀ sìí lọ́wọ́lọ́wọ́.
Àlùkò’ó fínní, ìbọn’ọn rẹ̀’ẹ́ fínní.