Ìtumọ̀ àjàbọ̀ọ́ ní èdè Yorùbá:

àjàbọ̀ọ́

Ohũ̀ /do do domi/

ɔ̀ɾɔ̀-oɾúkɔ

  • ìbọ́ láti ipò kan tí ó há (kù díẹ̀ kí ó má yọrí)

    Àjàbọ́ ni Donald Trump fi ṣe wà ní ayé lẹ́hìn tí ọkùnrin kan ta'á ní ìbọn ní ibí tí ó tí ń sọ̀rọ̀ ní gbangba.